EYIN OMO NIGERIA LO OKUNRIN, LO OBINRIN, ANFANI NLA RE OOO TI A TIN WA LATI OJO TO TI PE __KI AGBO OHUN TI IYA WA FE BAWA SO _ YEYE OSUN FATUNBI

             THRON MEGAN ALAAFIA
Malaika yi je ikan ninu ojise olodumare owa lati wa tun aye se lati ko fun oso, aje, ati gbogbo alaburu patapata malaika yi wa lati tun ori eniti ko dara se, ti eyan ba gba lati tele ilana malaika yi gbogbo ohun ti osoro fun iru enibe yi o di ayo ati idunnu,
Bakan na malaika thron ti aso ni pare yi ma n tu ohun gbogbo ti Awon elemi okunkun ba de, oma n yi gbogbo majemu ti Awon elemi okunkun base Lori aye eyan pada si rere fun eyan ti ofe thron se iyanu ninu aye ohun.
Epe si number yi 08038479685. 09081765981
          EGBE, ERE ARAGBO
TI aba soro nipa egbe oje ohun ti Ole se idiwo ni orisirisi ona, egbe le fa ki obinrin dara bi egbin ki oma ri oko tabi,ki okunrin mari aya fe, Ole fa koowo ma duro lowo eyan lai ni idi, egbe ma n fa ki ise mabo lowo eyan, ti iyawo baje elegbe ohun ti an so ama sele si oko pelu egbe ma n fa ki oyun ma baje lara obinrin tabi ki oma loyun rara,egbe tun ma nfa ki obinrin mabi abiku Eni ti oba je elegbe ama binu fufu ibinu yi ama ba nkan je fun enibe Eni ti o je elegbe ti ko fi idi egbe na lele. Awon nkan ti an so yi le ma sele si sugbon ti oba ti fi idi egbe na lele gbogbo nkanna yi oyi pada . Eni ti oba iyanju Lori egbe
Epemi. Sori ero ibani soro yi 08038479685 tabi 09081765981

                    OSUN
Osun onikin awede wemo-- osun je orisa ti oni anu pupo ti eniyan baje eniti odu osun bawa ni ori ree. Gbogbo nko re ama tuba. ama tuse. Gbogbo igba amari anu gba . Eni naa gbodo maa tooju osun loore koore. Osun je malaika ti on fun eyan ni omo. Owo. Gbogbo nkan rere ti eyan ba toro lowo osun ni oma n se fun yan. Eniti kori okofe ti oba ke osun aaa ri oko. Okunrin ti koba ri aya ti oba ke osun ari aya ti reee.              ...FUN EKUN RERE ALAYE  08038479685 tabi 09081765981

   OBATALA.  OSANLA. ODUA 
Obatala je malaika fun fun  ti ko ni abawon. Obatala je okan lara malaika ti oma n sise pelu olodumare. Ni idi eyi won ama pe ni ase oju se imu. Ti eyan ba ni aisan oju ti eni nah ba tete wa si idi obatala pelu agbara eledumare. Ati ase obatala oju naa ala rekete. Eyan ti oba ni stroke ti oba tete wa si odo obatala aisan naa Afi sile kia bi ogan. Obatala je oosa ti oma dabo bo eniyan fun Ekun rere alaiye  08038479685 tabi 09081765981

  OBALU AYE__ SONPONNON OLODE 
Malaika yi je aburo leyin gbogbo Malaika amon oje malaika ti ogboju kidi gann. Ti igbesi ayeyan ba le koko bi oju eja ti eni naa ba tete wasi odo obalu aye. Afefe ni malaika yi ma n ba sise . Malaika ti ansoro ree yi aman ki wipe pe. Opa aje. Opa oso. Opa ologun Ika. Atun ori Eni ti ko sun won se. Igbati aye ba gbe. ogun si eniyan malaika yi ma n segun, oma n dari owo si eniyan. Ona yi Owu. Ki eyan ba ni isoro ti oba ti de odo obalu aiye isoro nah alo. Eyi tun mo si wipe ti ogun bale koko obalu aiye ni oma n se 
     Fun Ekun rere alaiye  08038479685 tabi 09081765981
 } AJE
 }IFA
 } SANGO
 }ORISA OBALU
 } ESU
 } OGUN
 } EGUNGUN.  BEBE LO

Comments

Popular posts from this blog

LOVELY!!! Mercy Johnson Shows Off Her Baby Bump In Adorable New Photo

MEET MULTI TALENTED NOLLYWOOD ACTOR, PRODUCER CUM CONTINUITY MANAGER, SANUSI IZIHAQ ADEKUNLE __POPULARLY KNOWN AS { APANKUFOR } READ HERE @OGUNGBE FILMS